|
Lesson 2: Kíkí àwvn àgbà àti cni tí ó junilv.
Ìyábz: C káàárz o,
bàbá mi.
Bàbá Ìyábz: Káàrz o.
Xé ara mókun?
Ìyábz: B}| ni, ara mókun.
Bàbá Ìyábz: Xé o sùn dáradára?
Ìyábz: B}| ni, mo sùn dáadáa,
a dúp}.
Bàbá Ìyábz: Àwvn àbúrò rc
n k<?
Ìyábz: W<n wà
Bàbá Ìyábz: Xé w<n ti jí?
Ìyábz: W<n ti jí
Bàbá Ìyábz: Kò burú, tètè lv xe ìt<jú ilé.
Ìyábz: Kò burú (Ìyábz jáde)
(X}gun wvlé, ó dzbál|)
X}gun: C káàárz o
Bàbá Ìyábz: Xé dáadáa lo jí?
X}gun: B}| ni, a dúp}.
Bàbá Ìyábz: Xé àlàáfíà ni?
X}gun: Àlàáfíà ni.
Bàbá Ìyábz: Ìyá Ìyábz n k<?
X}gun: W<n
wà ní |hìnkùlé
Bàbá Ìyábz: Bá mi lv pè w<n
wá.
X}gun: Mo ti gb< o.
(X}gun jáde)
|
|