Supplementary
Materials
Unit 1: ÌKÍNI ÀTI
GBÍGBA ÀLEJÓ
-
Unit Dictum
-
Song: Báyìí làwa ń kóbi wà (This is
how we greet our parents)
-
Poem: Ìkíni (Greetings)
- Song: Káàbz! (Welcome!)
-
Word Maze Greetings word search
Unit Dictum: Cni tí kò kí ni kúulé, pàdánù c káàbz
“Whoever does not greet
the people at home will not receive a welcome”
Song: Báyìí
làwa ń kóbi wà
Verse One Báyìí làwa ń kóbi wà
Kóbiwà (2ce)
Báyìí làwa ń kóbi wà
Nígbà tìlc bá m<
Verse Two Zkùnrin a
d<bal|
D<bal|(2ce)
Zkùnrina d<bal|
Nígbà tìlc bá m<
Verse Three: Òbìnrìn a kún-unl|
Akúnl| (2ce)
Òbìnrìn a kún-unl|
Nígbà tìlc bá m<
Poem: Ìkíni
(Greetings)
Xe kíkí ni n kí i
yín ni,
Tàbí kíkì ni n kì
yín?
C kúulé, làá kí cni
abánílé
C káàbz sì lèsì fún
cni tó bá wà l<d|d|.
C kú ojúm< ni à
á kí ara cni ní àf|m<jú
C kú òwúrz ni à á
kí ara cni ní òwúrz
C kú zsán ni à á kí
ara cni ni zsán
Bí ó bá wá di
ìrzl}, à kí ara cni kúùrzl}
C kú ale ni à á kí
ara cni ni ale.
Ó dàbz, ó dìgbàkan
ná ni à á dágbére fára cni
Bí àkókò àtisùn bá
wá tó,
À kí ara cni pé, ‘Ó
dàárz.’
Song: Káàbz!
Ká àbz,xé dáadáa
lo dé? }
A ti n reti re } 2ce
ADÉTÒKUNBZ VMV ÒJÓ (insert
name)
Káàbz, xé dáadáa lo
dé? }
A ti n reti re (o) } 2ce
Greetings Word Search
1. Print and
see how many of these words you can find in the maze.
2. Use the
opportunity to also mark the right tones and diacritics on the words:
Ase (Amen / so be it) =
àxc Ogbeni (Mr.) = Zgb}ni
3. Remember,
the words can variously be arranged: forward or backward; horizontal or
vertical.
4. Then see how many other Yorùbá words you can find and gloss.
THE WORDS:
Ikini (Greeting) Dobale
(to prostrate) Kunle (to kneel down)
Kaabo (Welcome!) Kuule (greeting
for those at home) Kuuse (Well done)
Oruko (Name) Alaafia
(peace or good health) Ase (Amen
/ so be it)
Awaye (greeting for the
driver) Onile (host / house owner) Àlejò (guest)
Àredú (greeting for the
cloth dyer) Ogbeni (Mr.) Omidan
(Miss)
Amoye (greeting for the
smith) Ayaba (queen) Ojogbon (Professor)
Àrìnpa (greeting for the
hunter) Oba (King)
THE MAZE:
K U N L E N A D I M O B
A A O GB I K I K A A B O
D O R A K U U L E E B I
O M U I A L A A F I A O
B I K O N I L E D F W L
A M O Y E P G H A B A O
L A R I E S A W K GB Y P
E L N O J O GB O N T E I
K U B G O GB E J A Y F N
A A R I N E E Y E M O I
O W A Y I N E S U U K K
A Y A B A I O J E L A I