Home
Overview
Technical Help
Select Unit
>
Unit 2:
ÌMÚNI MVNI
>
Lesson 1:
Sisv nípa ara cni
Sis
v nípa ara cni
Adéb<lá:
Orúkv mi ni Adéb<lá vmv zgb}ni Babájídé
Mo j}
vkùnrin
Mò n
gbé
ní
abúlé
Zy<túnjí
Mo
wá
láti
ìlú
Ar<mvkv
ní
ìpínl|
Èkìtì
Ìpínl| Èkìtì wa ní
oríl| ède
Nàìjíríà
.
Vmv vdún mejìdínlógún ni mí.
Mò n gbé p|lú bàbá mi, màmá mi àti àwvn àbúrò mi méjì.
Mò n lv sí ilé ìwé
|k<
gíga
yunifásítì
ti ìpínl|
j<jíà
.
Vmv ìlú Nàìjíríà ni mí,
Xùgb<n
w<n bí mi sí ìlu
Tógò
.
Mo
f}ràn láti
máa xe
ìt<jú
ilé p|lú àwvn àbúrò mi
méjéèjì
.
Mo tún f}ràn láti máa
xeré
ní
àdúgbò
wa p|lú àwvn zr} mi vkùnrin àti
obìnrin
nígbà
ìsinmi
.