|
Kí ni N<nbà |rz ìbániszrz
rc?
Adédèjì: Kú ìrzl}, Bísí
Bísí: Kú ìrzl}, Dèjì
Adédèjì: Kí ni nnkan?
Bísí: Dáadáa ni. Ìwv n
k<?
Adédèjì: Alááfìà ní mo wà.
Bísí: Kú vj< m}ta o
Adédèjì: Vj< kan p|lú
Bísí: Ó p} tí mo ti rí c
Adédèjì: Bc|ni, ix} ni ó pz
Bísí: Xùq<n ixc kò ní ká maa rí ra
Adédèjì: Òt<< lo sv. Jzw<, má bínú.
Bísí: N kò bínú rára. Fún mi
ní n<nbà |rv ìbániszrz rc
Adédèjì: Kò burú, n<nbà mi ni eéjì, eéje, c}ta, oókan, eéjì, c}ta àti
c}rin
Mo ní n<nbà tìrc,
Eéjì, eéje, c}ta, aárùn-ún, oókan, oókan àti c}fà àbí?
Bísí: Ó tì o. N<nbà |rv ìbániszrz mi ti yàtz,
N<nbà mi titun ni eéji, eéje, c}ta, c}jv, eéje, c}rin àti c}rin
Adédèjì: Ó dára pé a lè szrz lórí |rv ìbániszrz
nísisìyí. Mo máa pè c láìp}
Bísí: Ó dára b}|. Ó dìgbà kan
ná
Adédèjì: Ó dìgbà
|
|