Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 2: > Lesson 6: Túnji pàde Táyz l<nà




    

Túnji pàde Táyz l<nà.

Túnjí:      Káàsán o Tayz
Táyz:      Káàsán. Báwo ni?
Túnjí:      Dáadáa ni. Níbo ni ò n lv?
Táyz:      Mò n lv sí ilé zr} mi tuntun.
Túnjí:      Kí ni orúkv zr} rc yì í?
Táyz:      Títílayz ni orúkv r|.
Túnjí:      Xé vmv il| yí ni? Níbo ni ó n gbé?
Táyz:      Ó n gbé ní òpópónà F}l}l|. Vmv il| yí nàá ni. Cgb<n r| n lv sí yunifásítì p|lú wa.
Túnjí:      Lóòt<! Ó dàbí cni pé o f}ràn vmvbìnrin yì í gan ò.
Táyz:      B}|ni, èrò mi ni láti fi xe olólùf}.
Túnjí:      Ó dára b}|. Vmv vdún mélòó ni vmvge yi.
Táyz:      Vmv vdún m}rìnlélógún ni, o l}wà púpz, O sì n ta vjà ni Gbági.
Túnjí:      O gbìyánju o, Vmvge tó rcwà, tó tún nix} l<w<.Níbo ni c ti pàdé?
Táyz:      A pàdé ní ilé zrc màmà mi. Jzw<, j} kí n tètè lv.Mo máa rí c l<gbà l<la.
Túnjí:      Kò burú. Ó dzla.
Táyz:      Ó dìgbà.