Unit 2:
NÍNÍ CBI
-
Unit Dictum
-
Song: Orin Cbí Kínní (Family Song I)
-
Song: Orin Cbí Kejì (Family Song II)
-
Word Maze Family word search
Unit Dictum: Cní bí ni làájv, àbíjv sì làá mv
ìtàn
“One can only resemble one’s
procreator/parent and it is physical resemblance that reveals (family)
history.”
Song: Orin
Cbí Kínní
Orin cbí (fún
vkùnrin)
Ènìyàn tí mo f}ràn
jù:
Ìyá mi, bàbá mi àti
ìyàwó mi,
>m< mi,
|gb<n mi, àtàbúrò mi.
adapted@Chief Ebenezer Obey
Song: Orin
Cbí Kejì
Bàba mi, iya mi,
cgbvn, } My
father, my mother, older sibling
Abúro mì } 3ce My younger
sibling
Gbogbo wvn j| cbi
mi. They are all my family
Family Word Search
1. Print and
see how many of these words you can find in the maze.
2. Use the
opportunity to also mark the right tones and diacritics on the words:
Omo (child) = Vmv ore (friend) =
Zr}
3. Remember,
the words can variously be arranged: forward or backward; horizontal or
vertical.
4. Then see how many other Yorùbá words you can find and gloss.
THE WORDS:
Baba (father) Egbon (older
sibling) Aburo (younger sibling)
Iyawo (wife) Oko (husband) Omo (child)
Mama (mother) Iya (mother) Yeye (mother)
Ebi (family) Aremo (first
born) Omokekere (Small Child)
Ore (friend) Afesona (fiancé) Ana (in-law)
Aladugbo (neighbor) Ojulumo (relative) Ara (relative)
Iyekan (relative) Ibatan
(relative)
THE MAZE:
O N A T A B I B A B O E
A K O B I Y A W O N M O
F R O Y A M O R E GB O B
E I E B I GB A M O P K I
S Y O M U L U J O R E Y
O E A F O GB U D M S K A
N N Y B A R A K O T E M
A I E A F E S A B U R O
O M Y B A A L S I W E W
J I N E GB O N M A M A A
U L U M O N A E Y E Y G
L A L A D U GB O B A B A