Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 3: NÍNÍ CBÍ > Exercise 1:


Review Lesson 1 and choose the option that best complete each of the following:

        1. Orúkv àwvn vbí Adéwálé ni:

        A. Arábìnrin Títílayz àti Olóyè Adéògún
         
        B. Olóyè Adéògún àti Toyin
         
        C. Arábìnrin Títílayz àti Tolú
         
         
        2.Orúkv àwvn àbúrò Adéwálé ni:

        A. Tádé, Adéògún àti Tolú
         
        B. Tádé, Tóyìn àti Títílayz
         
        C. Tádé, Tóyìn àti Tolú
         
         
        3. Nínú cbí Adéwálé, àwvn vkùnrin ni

        A. Olóyè Adéògún, Adéwálé àti Tóyìn
         
        B. Olóyè Adéògún, Adéwálé àti Tádé
         
        C. Olóyè Adéògún, Adéwálé àti Tólú
         
         
         
        4. Ninu cbi Adéwálé, awvn obinrin ni

        A. Arábìnrin Títílayz, Tolú àti Tóyìn,
         
        B. Arábìnrin Títílayz, Tólú àti Tádé
         
        C. Arábìnrin Títílayz, Tólú àti Adéwálé
         
         
         
        5. Cbí Adéwálé n gbé ní

        A. Òndó
         
        B. Ògùn
         
        C. Zwz
         
         
        6. Cbí Adéwálé kò

        A. sanra
         
        B. kéré
         
        C. tóbi
         
         

 

© African Studies Institute, University of Georgia.