|
Àwòran bàbá àti ìyá mi
ni.
Olúx}gun: Adéwálé, kí nì ycn?
Adéwálé: Àwòrán bàbá àti ìyá mi
nì. (Showing picture of family
to Olúx}gun)
Olúx}gun: Níbo ni wvn n gbé?
Adéwálé: W<n n gbé ní Òndó
Olúx}gun: Xe cbí rc tóbi?
Adéwálé: O
ti,
cbí mi kò tóbi rárá,
Mo
ní bàbá, ìyá àti àbúrò m}ta.
Orúkv àwvn òbí mi
ni Olóyè Adéògún àti Arábìnrin Títílayz
Orúkv àwvn àbúrò mi ni Tádé, Tóyìn àti
Tólú. Tade j} vkùnrin
xùgb<n obìnrin ni Toyin ati Tolu.
Gbogbo wvn
n gbé ní ìlú Òndó p|lú àwvn òbí mi.
Xé o ri wí pé cbí mi kéré. J}
k’a lv kí àwvn òbí mi.
Olúx}gun: Kò burú (W<n jade)
|