Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 3: Cbi Tó Gbòòrò (Broader Family) > Lesson 3: Kíni orúkv àwvn ìyàwó yín yókù?




    

Kíni orúkv àwvn ìyàwó yín yókù?

Zjzgb<n Fákúnlé:       Olóyè Àkànmú! C kú vj< m}ta o.
Olóyè Àkànmú:           Vj< kan p|lú. Gbogbo ilé n k<?
Zjzgb<n Fákúnlé:      Àlàáfíà ni a wà, c xeun.
Olóyè Àkànmú:           Xé ix} ìwádìí ìjìnl} n lv dáadáa?
Zjzgb<n Fákúnlé:      Ó n lv dáadáa. À wvn ìyáàfin n k<?
Olóyè Àkànmú:           Àlàáfíà ni àwvn m}t||ta wa.
Zjzgb<n Fákúnlé:      Àwvn m}t||ta k|? N kò mz wipé ìyàwó m}ta ni c ní.
 
                          Ìyáàfin Fálvlá àti àwvn vmv wvn m}r||rin nìkan ni mo
mz?
Olóyè Àkànmú:          Ìyàwó m}ta ni mo ní nísìsiyìí. Mo ti f} ìyàwó méjì míràn  
   
                               l}yìn Fálvlá.
                                   Fálvlá ni ìyàálé báyìí.
Zjzgb<n Fákúnlé:     N kò mz rárá. Ojú tó rí i yín ti gbó o. Kíni orúkv àwvn ìyàwó yín yókù?
Olóyè Àkànmú:  
     Fáník|} ni orúkv ìyàwó mi keji. Ó ti bí vmv méjì fún mi.
 
                          Orúkv ìyàwó mi kékeré ni Fáxèyí, oun naa ti bí vmv méjì fún mi.
Zjzgb<n Fákúnlé:     Ó dára púpz. C kú ìt<jú gbogbo ilé o. È dùmàrè, á máa pèsè o.
Olóyè Àkànmú:          Àxc o. C xeun.
Olóyè Àkànmú:          Ìyàwó àti àwvn vmv tiyín náà n k<?
Zjzgb<n Fákúnlé:     W<n wà.
Olóyè Àkànmú:          Inú mi dùn púpz láti rí i yín, Zjzgb<n Fákúnlé.
 
                          C bá mi kí gbogbo àwvn ará ilé o.
Zjzgb<n Fákúnlé:     Wvn á gb< o.Vp} ní fún Vl<run. Ó dìgbà kan ná o.
Zjzgb<n Fákúnlé:     Ó dìgbà.


© African Studies Institute, University of Georgia.