|
Mo ní àbúrò m}fà àti cgb<n
kan.
Olúx}gun:
Orúkv mi ni Olúx}gun vmv Àkànmú.
Mo ní cbí tí ó tóbi dí|.
Mo ní |gb<n kan àti àbúrò m}fà.
Bàbá mi, Olóyè Àkànmú, ní ìyàwó m}ta
Màmá mi ni ìyàále.
Orúkv wvn ni Arábìnrin Fálvlá,
W<n bí àwa vmv m}rin.
Àwvn ìyàwó yókù ni arábìnrin Fáník|} àti arábìnrin Fáxèyí.
W<n bí vmv méjìméjì, vkùnrin kan àti obìnrin kan.
Ní àpapz, vmv m}jv ni
bàbá à mí bí,
Vkùnrin m}rin àti obìnrin m}rin.
Gbogbo àwvn ìyàwo bàbá mi ni w<n ní omokunrin ati omvbìnrin.
Èmi ni vmv kejì nínú cbí mi.
Orùkv ègb<n zn mi ni omidan Vmvl|yc.
Mo ní àbúrò vkùnrin m}ta.
Orúkv wvn ni Olúwálé, Olúdámiláre àti Olúxvlá
Mo tún ní àbúrò obìnrin m}ta.
Orúkv wvn ni Vmvlará, Vmvlayz àti Vmvlolú.
Vmv ìyá kan
náà ni cgbvn mi, emi,
Olúwálé àti Vmvlará.
Vmv ìyá kan náà ni Olúdámiláre àti Vmvlolú,
Arábìnrin Fáník|} ni màmá wvn.
Vmvlayz àti Olúxvlá sì j} vmv arábìnrin Fásèyí.
Vmv baba ni èmi, |gb<n mi àti gbogbo àwvn àbúrò mí j}.
Mo f}ràn gbogbo cbí ì mi púpz gan an ni.
|
|