Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 3: NÍNÍ EBÍ> Lesson 5: Àwòjúwe cbí Zmzwé Y}misí Òjó




    

Àwòjúwe cbí Zmzwé Y}misí Òjó

Ebí mi (Òmòwé Y}misí Òjó)
Mo Bàba bàbá, orúkv wvn ni Alàgbà Adéníran Òjó.
Mo ní Màma bàbá, orúkv wvn ni Arábìnrin Abímb<lá Ojo.
Bàba bàbá àti màma bàbá mi n gbe ní Ìlvrà ní ìlu Nàìjíríà.
N kò ní bàba màmá àti màma màmá nísìsiyìí, w<n ti xe aláìsí.
Orúkv wvn ni Alàgbà àti Arábìnrin T|llà,
W<n gbé ní Ìbàdàn ní ìlu Nàìjíríà nígbà ayé e wvn.

Mo ní bàbá, orúkv wvn ni Olóyè Bámijí Òjó.
W<n wá láti Ìlvrà ní ìlu Nàìjíríà.
W<n n gbé ní Ìbadàn ní ìlu Nàìjíríà.
Bàbá mi ní |gb<n méjì, vkùnrin kan àti obìnrin kan.
Orúkv wvn ni Zgb}ni Adéníyì Òjó àti Arábìnrin Oyinlvlá
Arábìnrin Oyinlvlá ti xe aláìsí.
Bàbá mi ní àbúrò obìnrin m}ta. Orúkv wvn ni Arábìnrin Oyèládùn, Arábìnrin Oyègbónjú, àti Arábìnrin Adérónk}.
Àwvn |gb<n àti àbúrò bàbá mi n gbé ní ìlu Nàìjíríà.

Mo ní màmá, orúko won ni Arábìnrin Fadérera Òjó.
W<n wá láti Fìdítì ní ìlu Nàìjíríà
W<n n gbé ní Ibàdàn ní ìlu Nàìjíríà.
W<n ní àbúrò obìnrin m}ta. Orúkv wvn ni Arábìnrin Adéfúnké, Arábìnrin Adéyínká àti Arábìnrin Adéolá.
Arábìnrin Adéyínká ti xe aláìsí.
Màmá mi kò ní |gb<n rárá, wvn kò sì ní |gb<n tàbí àbúrò vkùnrin kankan.

Àwvn obí mi ní àwa vmv márùn-ún, èmi àti àwvn àbúrò mi mérin.
Èmi ni àk<bí.
Mo ní àbúrò m}rin; obìnrin m}ta àti vkùnrin kan.
Orúkv àwvn àbúro mi obìnrin ni Arábìnrin Oyèbímpé, Arábìnrin Vdúnayz,
àti Arábìnrin Tèmít<p}.
Orúkv àbúrò mi vkùnrin ni Arákùnrin Oyèdèjì.
Gbogbo wón n gbé ní Ibàdàn ní ìlu Nàìjíríà,
W<n j} ak}kz< ní yunifásítì.

© African Studies Institute, University of Georgia.