|
Vmv àbúrò màmá mi.
(At a rest stop)
Túnjí: Tayz, ta ni a
wá pàdé gan ná?
Táyz: Vmv àbúrò màmá mi,
Adéwálé ni. Ó sv pé òun f} wá kí mi l<gbà
yunifásítì.
Túnjí: Xe vmvdé ni
tàbí àgbàlagbà?
Táyz: Vmvdé ni. Vmv vdún márùndínlógún ni.
Túnjí: Báwo ní c
xe tan?
Táyz: Bába rc, Olóyè Adéògún, ni àbúrò màmá mi
Zdv wvn
ni mo gbé láti vmv vdún m}ta títí di
vmv vdún méjìlá
O n lv sí ilé ìwé. Ilé ìwe
oníwè m}wàá ti Àpáta ní Ìbàdàn ni ó n lv.
Adéwálé náà ló dé yìí (Adéwálé arrives and greets Táyz).
Adéwálé: C kúulé o, bùrzdá Táyz
Táyz: Káàbz
o, Adéwálé. Xé dáadáa lo dé?
Adéwálé: A dúp}, c xé.
Táyz: Kí zr}
mi, Túnjí.
Adéwálé: C kúùrzl} bùrzdá.
Túnjí: Kúùrzl}.
Xe dáadáa ni?
Adéwálé: Dáadáa ni, a dúp}
Túnjí: Ilé ìwé n k<?
Adéwálé: O n lv dáadáa, c xé.
Túnjí: Àwvn òbí rc,
Olóyè Adéògún àti Arábìnrin Adék}mi n k<?
Adéwálé: Àlàáfíà ni wvn wà.
Táyz: O dára. } j} ká lv. Kú ìrìn
Adéwálé: C xé. |
© African Studies
Institute, University of Georgia.
|
|