Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 4: ÒNKA YORÙBÁ > Exercise 3: Part two


Part One: Review Lesson 4 and answer the following questions:

    1. nnkan mélòó ni ó wà nínú àpò ak}kz< yì í?

    A. nnkan màrún
     
    B. nnkan m|fà
     
    D. nnkan mókàndínlógún
     
     
    2. Sáà mélòó ni àwvn ak}kz< gb<dz fi k< Yòrùbá?

    A. Sáà m|rin
     
    B. Sáà meji
     
    D. Sáà mejila
     
     
    3. Kí ni ó wà nínú w<l}|tì ak}kz< yì í?

    A. Ogoji d<là àti axv ìnumú méjì,
     
    B. Ogún d<là àti axv ìnujú méjì,
     
    D. Ogvfa d<là àti axv ìnuri méjì
     
     
     
    4. Ak}kz< mélòó ni ó wà ní kíláàsì Yorùba r|?

    A. Ak}kz< m|rin
     
    B. Ak}kz< mèje
     
    D. Ak}kz< m|wá
     
     
     
    5. Kíláàsì mélòó ni ak}kz< yì ní?

    A. Kíláàsì méjì
     
    B. Kíláàsì m|ta
     
    D. Kíláàsì m}rin
     
     
 

© African Studies Institute, University of Georgia.