|
Lesson 3 Nnkan mélòó ni ó wà nínú àpò rc?
Zgb}ni Adébzwálé: Kíláàsì mélòó ni o ní lónì í?
Ak}kz<: Kíláàsì m}ta ni mo ní.
Mo ní kíláàsì bày<l<jì, kíláàsì ìxirò àti kíláàsì Yorùbá.
Zgb}ni Adébzwálé: N kò mz wípé | n xe kíláàsì Yorùbá ní ilé ìwé rc.
Sáà mélòó ni c fi n k< v?
Ak}kz<: Gbogbo àwa ak}kz< ni a gb<dz k< Yorùbá fún sáà méji, ó kéré tan.
Zgb}ni Adébzwálé: Ó dára púpz.
Ak}kz< mélòó ni ó wà ní kíláàsì tìrc?
Ak}kz<: Àwa m}wàá ni a wà ní kíláàsì Yorùbá ní sáà yí.
Zgb}ni Adébzwálé: Kò burú.
Xé o lè dáhùn ìbéèrè yìí?
Ak}kz<: Kí ni ìbéèrè náà?
Zgb}ni Adébzwálé: Ó dára, qé àpò rc wá
Ak}kz<: Àpò mi nì yí
Zgb}ni Adébzwálé: Xé o lè ka àwvn nnkan tó wà nínú àpò rc?
Ak}kz<: B}|ni, mo lè kà w<n.
Zgb}ni Adébzwálé: Ó yá, kà w<n fún mi.
Ak}kz<: Mo ní ìwé m}fà, l}|dì m}ta, kálámù méjì, ìpàwér} kan,
rúla kan, àpò ìwé márùn àti w<l}|tì kan wà nínú àpò mi.
Ogún d<là àti axv ìnujú méjì sì wà nínú w<l}|tì mi.
Zgb}ni Adébzwálé: O káre. |