Unit 3:
ÒNKA YORÙBÁ
-
Unit Dictum
-
Poem: Ení bí Ení (one by one)
-
Poem: EnÍ bÍ enÍ lvmvdé n kawó (It is 1-by-1 that
children count money)
-
Word Maze Numbers word search
Unit Dictum: Ení bí ení , lvmvdé n ka owó ; è jì bí
è jì , là gbà lagbà n ta ayò .”
“Children count money in singles;
adults play in pairs.”
Poem: EnÍ
bÍ EnÍ
EnÍ bÍ enÍ; Èjì
bí è jì ;
Cta n tagbá ; Crin
wzrzkz,
Àrú n n gbó dó ; Cfà
tí è lè ;
Àró n bá ró ; Àro
n bà tá ;
Mo já lá k|sá n; Gbagba
l|wá .
Poem: EnÍ
bÍ enÍ lvmvdé n kawó
Ení bí ení , l’vmvdé
ń kawó
Èjì bí è jì ,
l’à gbà lagbà ń tayò
cta bí |ta, cj} k’á
tara wa l<rc
Crinbí |rin, cní
rí n ni l’à ń rí n
Àrú n bí à rú n, vba
má xe wá l’á rungú n
Cfà bí |fà , cj} k’á
fara wa m<ra
Èje bí è je,
olú gb<n xorò ó kì je
Cjv bí |jv, cní bí
‘ni l’à á jv
Csá n bí |sá n, Olú wa
já l} ó san wá
Cwá bí |wá , vba má
wà há là wa
Number Word Search
1. Print and
see how many of these words you can find in the maze.
2. Use the
opportunity to also mark the right tones and diacritics on the words:
Ogbon (thirty) = Vgbzn Aabo (half) = Àabz
3. Remember,
the words can variously be arranged: forward or backward; horizontal or
vertical.
4. Then see how many other Yorù bá words you can find and gloss.
THE WORDS:
Odo (zero) Eni (one) Okan
(one)
Kinni (first) Eewaa (ten) Okanla
(eleven)
Eedogun
(fifteen) Ogun
(twenty) Okoo (twenty)
Ogbon (thirty) Idaji (half) Aabo
(half)
Onka (numerals) Nonba (numbers/numerals) Meloo?
(How many?)
Eeloo?
(How much?) Keloo? (Which
position?) Keji (second)
Mejimeji
(in pairs) Mejeeji (both)
THE MAZE:
E M O K A N L B M A S M
M E J E E J I O O K E E
E GB D J A A B A GB I E J
L I H O D O O T O N L I
O N T A G R G I GB N A M
O E D E M U U J O I M E
P I E J I L N O N B
A J
O W A L N A K O P A R I
N A M A O E E W A A S E
K I GB A GB O A A D O T A
A B O O K O K E L O O B
K E J I R O R I J A D I