|
Eélòó ni | n ta |gbà vw<?
Oníbàárà: C
kú ojúmv o, bàbá Vl<jà.
Bàbá Vl<jà: C káàbz o. X’àlàáfíà ni?
Oníbàárà: Àlàáfíà ni o. Xé c tà?
Bàbá Vl<jà: A dúp}. Kí ni c f} rà?
Oníbàárà: Mo f} ra |gbà vw< fún ìyàwó mi.
Bàbá Vl<jà: Irú |gbà vw< wo lc f}? Mo ní |gbà vw< oníwúrà àti onífàdákà.
Oníbàárà: Oníwúrà ni ìyàwó mi f}. O f}ràn góòluù gan
an ni.
Bàbá Vl<jà: Kò burú. Mo ní |gbà vwv oníwúrà.
Oníbàárà: Eélòó ni | n ta àwvn |gbà vwv yín?
Bàbá Vl<jà: Náírà m}jvm}jv ni.
Oníbàárà: Mo f} |gbà vwv tínnrín méjì.
Bàbá Vl<jà: Ó dára. O j} náírà m}rìndínlógún.
Oníbàárà: Xe kò gba náírà m}fàm}fà ni?
Bàbá Vl<jà: Náírà m}jvm}jv ni.
Oníbàárà: Xé mo le è san náírà m}fà ààbz fún ìkzvkan?
Bàbá Vl<jà: O tì o. Náírà méjeméje ni
jál|.
Oníbàárà: Ó gba náírà méjeméje?
Bàbá Vl<jà: B}|ni, c sanwó.
Oníbàárà: C gbà, náírà m}rìnlá nì yí.
Bàbá Vl<jà: C xeun. Cgbà vwv oníwúrà tínnrín
méjì nì yí.
Oníbàárà: Ajé á wv gbá o.
Bàbá Vl<jà: Àxc o. Ó dàbz. |
© African Studies
Institute, University of Georgia.
|
|