Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 5: RÍRÀ ÀTI TÍTÀ > Lesson 2: Báwo ni o xe máa n ná vjà dáradára báyìí.




    

Báwo ni o xe máa n ná vjà dáradára báyìí.

B<látitó:      Fvláxadé, kí ni o lv rà l<jà lánàá?
Fvláxadé:   Mo lv ra àpò ilé ìwé fún àbúrò mi.
B<látitó:      Xé ó w<n tàbí o rí i l<pz?
Fvláxadé:   Ó w<n dí| xùgb<n mo ná a dáradára.
B<látitó:      Eélòó ni o rà á?
Fvláxadé:   Vg<rin náírà ni mo san.
B<látitó:      Kò w<n jù. Eélòó ni alápò dale àpò yí?
Fvláxadé:   Vg<jv náírà ni o k<k< bèèrè.
B<látitó:      O wá ná a wal| sí vg<rin náírà?!
Fvláxadé:   B}|ni, èmi náà rò pé mo ná a dáradára.
B<látitó:      O ná a dáradára púpz. Báwo ni o xe máa n ná vjà dáradára báyìí?
Fvláxadé:   Ko xòro rárá.
B<látitó:      Jzw< xàlàyé e r| fún mi.
Fvláxadé:   Bí vl<jà bá ti sv iye tí o f} gbà fún vjà r|,
                       Mo máa bèèrè bóyá mo lè san iye tó kéré púpz
                       Vl<jà máa kv iye tí mo sv yi,
                       ó sì máa sv iye míràn.
                       L}yìn èyí ní mo máa b|r| sí xàlàyé pé ak}kz< ni mí,
                       N kò sì ní cnìkankan láti fún mi lówó púpz.
                       Gbogbo àlàyé yìí àtí kíkó owó jade lápò ni znà
                     
tí mo máa n gbà láti ra nnkan ní |dínwo tàbí ní zpz l<jà.
B<látitó:      Èmi náà máa gbìyànjú láti lo znà ìnájà rc yì í ní vj< kan láìp}.
Fvláxadé:   Kò burú. J} ká lv kí Vm<ycmí
B<látitó:      Ó dára.

© African Studies Institute, University of Georgia.