Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 5:RÍRÀ ÀTI TÍTÀ > Lesson 4: Mo ra ìlé ata méje




    

Mo ra ìlé ata méje.

Vmvtoók}:àna, mo pinnu láti se vb} aláta.
Mo múra, mo lv sí vjà Òjé.
Mo f}ràn láti ra nnkan ni vjà yí púpz.
Àwvn àgb| àti oríxìríxi ìnájà ní wvn n tà nnkan ní vjà Òjé,
Nítorí náà, w<n máa n ta vjà wvn ní |dínwo.
W<n n ta oríxìríxi nnkan oúnjc àti àwvn ohun èlò vb| ní vjà yi.
Gbogbo ènìyàn lè ra nnkan ní zpz.
Mo ra cran náírà marùndínlógójì ní ìsv àwvn clcran.
L}yìn náà, mo lv sí ìsz àwvn aláta.
Mo ra ìlé ata méje;
Mo ra ìlé tàtàxe méjì, ìlé rodo méji àti ìlé tòmátì m}ta.