Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 5:RÍRÀ ÀTI TÍTÀ > Lesson 5: Kaba tí mo rà, kò w<n rárá




    

Kaba tí mo rà, kò w<n rárá

Olúwar|míl}kún: Mo lv sí x<zbù òde òní kan láti ra axv.
A kìí naá vjà ní x<zbù yí,
Nítorí wípé gbogbo ohun tí wvn n tà ni w<n ti fiyelé.
W<n sì máa n lc òntc owó wvn m< wvn lára
Xùgb<n àkókò tí mo lv j} àkókò vdún,
Wvn n ta gbogbo vjà wvn ní |dínwó.
Kaba tí mo rà kò w<n rárá.
Nígbà míràn, kaba náà á j} vg<ta d<là
Xùgb<n ní àkókò vdún yì í, mo san ìdajì owó r|,
Vgbzn d<là ni w<n gbà fún un!
Funfun àti pupa ní àwv kaba yì í,
Ó gùnìwznba, ó sì xe r}gí lára à mi.
Mo f}ràn Kaba náà púpz.
Bí ó til| j} wípé kò sí vjà níná ní x<zbù yí,
Mo máa n dúró di ìgbà tí w<n bá n xe àjzdún tàbí èto |dínwó vjà
Kí n tó lv ra nnkan níb|.