Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 5:RÍRÀ ÀTI TÍTÀ > Lesson 6: Gbogbo Àwvn ìwé wzn ni w<n ní iye owó wvn lára.




    

Gbogbo Àwvn ìwé wzn ni w<n ní iye owó wvn lára.

Vdúnayz:   Tèmít<p}, Ilé ìtàwé yì í tóbi ju Ilé ìtàwé ti yunifásítì wa lv.
Tèmít<p}:   B}| ní. Kódà, mo gbv pé ibí yì ni àwvn oxìs} ilé ìkàwé wa ti máa n ra àwvn ìwe wvn.
Vdúnayz:   Xé ìwé kò wvn púpz níbí yì í ni?
Tèmít<p}:   B}| ni. Àwvn ìwe wvn kò w<n rárá.
                       Gbogbo àwvn ìwé wzn ni w<n ní iye owó wvn lára.
Vdúnayz:   Lóòt< ni, ogójì náírà ni ìwe atúmz ède Yorùbá yi.
                       Nj} o mz pé vg<ta náírà ni Ilé ìtàwé ti yunifásítì wa?
Tèmít<p}:   Xe mo sv fún c. Ìwé wo ni o f} rà gan ná?
Vdúnayz:   Ìwé ewì Àròyé Akéwì Kejì tí Akéwì Túnbzsún Vládàpz kv ni mo f} rà.
Tèmít<p}:   Ó yc kí èmi náà ra ìwé náà. J} kí á fi arabal| wa
Vdúnayz:   Hcn hcn! òun nì yí.
Tèmít<p}:   O káre. Eélòó ni?
Vdúnayz:   Náírà márùndínl<gbzn ni ó wà lára r|.
Tèmít<p}:   Kò w<n rárá. J} kí á lv sanwó.