Unit 5: RÍRÀ ÀTI TÍTÀ
-
Unit Dictum
-
Song: Báyìí làwa ń lv svjà (This is
how we go to the market)
-
Word Maze: Buying and Selling Word
Search
Unit Dictum: Gba wèrè, n kò gba wèrè lariwo vjà
fi n hó/pz.
“It is the refusal to be cheated (in bargaining) that causes
the noise in
the market.”
Song: Báyìí
làwa ń lv svjà
1. Báyìí
làwa ń lv svjà
L< svjà
(2ce)
Báyìí làwa ń lv svjà
Nígbà tìlc bá m<
2. Onìbàra á najà
Á najà (2ce)
Onìbàra á najà
L<w< òníxowó
3. Zlzjà a rí erè
Rí éré (2ce)
Zlzjà a rí erè
Kójú àja tó tú
Buying and Selling Word Search
1. Print and
see how many of these words you can find in the maze.
2. Use the
opportunity to also mark the right tones and diacritics on the words:
Owon
(dear/expensive) = Zw<n Iso
(stall) = Ìsz
3. Remember,
the words can variously be arranged: forward or backward; horizontal or
vertical.
4. Then see how many other Yorùbá words you can find and gloss.
THE WORDS:
Onibara (customer) Ipolowo
(advertisement) Aje (profit)
Naira (Nigerian
currency) Dola (American currency) Oja
(market)
Kobo (Nigerian
currency) Senti (American currency/cent) Owo
(money)
Soobu
(shop) Iso (stall) Oloja
(seller)
Ate (tray/wares) Igba (calabash/wares) Ootee (stamp)
Owon (dear/expensive) Alapata (butcher) Lebeeli
(label)
Oniso (stall
owner) Edinwo (discount/reduced price)
THE MAZE:
E T A L A R O O T O E S
W D L O N I B A R A D E
E S I N A O O T E E I N
O W O N L T K A B A N T
L E B E W E R O A GB E I
O R U A GB O O W B U B A
J L GB F N W O B A O K S
A I E I O S N A I R A O
F K S L E B E E L I L O
I O O A J A GB
E O R A B
N P L U D O L A J E P U
I N A L A P A T A P A L