Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 6:AXV WÍWZ ÀTI OGE XÍXE > Lesson 1: A wv àwzkanl| axv òkè.




    

A wv àwzkanl| axv òkè.

Arábìnrin Kúy|:     Báwo ni, zr} mi àtàtà.
Arábìnrin Fvlárìn:  Dáadáa ni o. C kú vj< m}ta
Arábìnrin Kúy|:     Vj< kan p|lú. Gbogbo ilé n k<?
Arábìnrin Fvlárìn: Àlàáfíà ni w<n wà. Ojú tó rí c gbó o. Má bínú, znà pz.
                                  A x|x| xe ìnáwó ìyàwo vmv zrc vkv mi kan ni.
Arábìnrin Kúy|:      N kò bínú rárá.
Arábìnrin Fvlárìn:  Èmi ni mo xe gbogbo èto axv tiwa àti ti zr} vkv mi
                                  p|lú ìyàwó r|.
Arábìnrin Kúy|:      Ix} n lá nìycn o. Irú axv wo ní c wz?
Arábìnrin Fvlárìn:   A wv àwzkanl| axv òkè pupa àti funfun.
                                   Àwa obìnrin wv bùbá funfun p|lú ìborùn funfun
A ìro pupa,
                                   a sì gèlè pupa.Àpò àti bàtà kan náà la tún lò.
Arábìnrin Kúy|:      Xe axv òkè náà ni àpò àti bàtà yín?
Arábìnrin Fvlárìn:   Ó tì o. Awv ní w<n fi xe àpò àti bàtà wa.
Arábìnrin Kúy|:      Ó le kú! Àwvn vkv yín n kv?
Arábìnrin Fvlárìn:   Bákan náà ni.
                                      Àwvn méjéèjì wv bùbá àti xòkòtò funfun W<n sì dé fìlà pupa p|lu u bàtà dúdú.
                                      A gbayì, a gb|yc, axv Yorùbá yc wa púpz.

© African Studies Institute, University of Georgia.