|
Èto
ojúxe e mi lójoojúm<.
Vláyíwvlá: Orúkv mi ni Vláyíwvlá Adéníji.
Mo j} vmv
ilé ìwé yunifásitì ti ìpínl| Èkó.
Báyìí ni mo xe n lo àkókò mi lójoójúm<.
Ní òwúrz,
mo máa n jí ní nnkan bí i aago m}sàn-án àárv,
Mo máa k<k< xe àdúrà kí n tó fi orí ìbùsùn mi síl|.
L}yìn náà, mo máa wá lv sí balùw| láti xe ìt<jú ara.
Mo máa fv eyín
mi, mo sì máa wc.
Nígbà tí mo bá w| tán,
mo máa múra.
Mo f}ràn láti jc oúnjc àárz kí n tó jade.
Ní aago m}wàá abv, mo máa lv sí kíláàsì mi àk<k<.
Tí ó ba di aago méjìlá, mo máa lv sí ibi ix} fún wákàtí méjì.
Ilé oúnjc àwvn àk}kz< ni
mo ti n xis}.
Níb| ni
mo ti máa n jc ounjc zsán.
Láti aago méjì àbz zsán títí di nnkan bí i aago m}fà àbz ìrzl},
Mo máa n lv si àwvn oríxiríxi kíláàsì mi,
Mo sì máa n xeré p|lú àwvn zr} mi.
Ní vj< míràn, mo lè kàwé dí| ní ilé-ìkàwé.
Lójoojúm<, mo máa n padà sí yàrá mi
ní aago m}jv al}.
Bí mo xe n lo àkókò mi lójoojúm< nìyí.
|
|