|
Àkókò ayé e
wa.
Akéwì: Àkókò ayé e wa.
Zr} mi, àsìkò kò dúró de cnìkan,
bí il|
xe n sú ni il|
n m<.
Vj< n gorí vj<,
B}| sì ni vl<j< n kaj<.
Tí a bá bí vmv lónìí,
Kí á tó rí vj< méje, ó ti pé vmv zx| kan.
Ni zx| m}rin, a á pé vmv oxù kan.
Kí á tó mz, lóxù méjìlá, vmv a pe vmv vdun kan.
Àkókò ayé ènìyàn dàbí àkókò nínú vj<.
Òwúrz nìgbà vmvdé,
Zsán nìgbà zd<,
Ìrzl} ni tí a bá dàgbà.
Vj< ogbó ni
vj< al}.
Gbogbo ohun tí a bá xe láàárz ayé e wa,
Ni yóò bá wa dal}.
Má gbàgbé wípé àsìkò lvj<.
|
|