Yéwándé: Zr}
mi tím<tím< ni Àmzlé.
Gbogbo ìwa r|
ló dára púpz.
Xùgb<n ohun tí mo f}ràn jù nipé
Àmzlé j} obìnrin onímz<tótó.
Ó máa n xe ìt<jú ara r|
l<pzlvpz,
A á w|, a á kàtíkè,
A á sì fi ìparaolóòórùn dídùn para.
Ènìyàn dúdú ni Àmzlé,
Ojoojúm< ni ara r| máa n dán. Èékánná r|
máa n wà ní gígé ní gbogbo ìgbà.
B}| sì ni, ó máa n dí irun r| tàbí kí ó kó o.
Ó máa n múra bó xe t< àti bó xe yc ní ìgbà gbogbo.
Zr} mi, Àmzlé, gbàgb<dájúdájú pé, Ìm<tótóboríàrùnm<l|g}g}bí Vy} xe n borí ooru.