Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 7:ÈTÒ OJÚSE OJOOJÚM> ÀTI ÌT>JÚ ARA > Lesson 6: B<látitó wv axv aycyc r| níjcta




    

B<látitó wv axv aycyc r| ní ìjcta.

Adétóun:   Káàsan, zr} mi.
Modúp}:    C káàsán o, xé ajé n wá?
Adétóun:   C xé, adúp}. Xé o ti wv axv tí mo bá c rán?
Modúp}:    B}| ni, mo wz w<n lánàá.
Adétóun:   Xé ó v mu?
Modúp}:   B}| ni o, xùgb<n kò dàbí i ti B<látitó.
Adétóun:   Xé o rí tir| l<rùn r| ni?
Modúp}:    B<látitó wv axv aycyc r| ní ìjcta.
                     Mo rí i ní ilé ìtura tó wà ní Ìdí ixin.
                    Gbogbo àwvn ènìyàn tó rí i, ni w<n f}ràn r|.
Adétóun:   Kílo f}ràn nínu ìmúra B<látitó?
Modúp}:   Mo f}ràn bí c xe rán vw< buba r|, Mo tún
                      níf| vnà tí c xe síwájú àti |hin ìro r|.
Adétóun:    Kò burú, mú axv tì c wá l<la, Màá tún xe.
Modúp}:     Mo tún f}ràn gèlè àti bàtà tó bá awv axv B<látitó mu.
Adétóun:    Ó tì o. Òun ni ó mú gèlè àti bàtà fún ara r| o!
Modúp}:     Ní tòót<? B<látitó f}ràn oge gan an ni ò.