Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 8: ÀWVN ÌBÁTAN ÀTI ÀWVN ÀJVXE MÍRÀN> Exercise 5:

Exercise 5: Review Lesson 5 and state whether these statements about Táyz Adélàjà are TRUE or FALSE (B}| ni tàbí B}| k<).


1. Táyz n gbé ní ìlu Ayétòrò. B}| ni B}| k<
2. Vmv vgbzn vdún ni Táyz B}| ni B}| k<
3. Táyz kì í xe zr} tòótó B}| ni B}| k<
4. Táyz kì í pur<, kì í sì jalè B}| ni B}| k<
5. A lè pe ìdílé Táyz ní Vl<rz B}| ni B}| k<
6. Àwvn cbí Táyz j} aláàánú àti onít|l<rùn B}| ni B}| k<
7. Agboóle àwvn Táyz wà l<nà Ààfin Vba Ayétòrò B}| ni B}| k<
8. Táyz kò lv sí ilé ìwé |k< gíga B}| ni B}| k<
9. Táyz kì í xe cni tí a lè f|hìntì B}| ni B}| k<
10. Táyz n k< |k< òxèlú ní ilé ìwé |k< gíga B}| ni B}| k<

 

© African Studies Institute, University of Georgia.