Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 8:ÀWVN ÌBÁTAN ÀTI ÀWVN ÀJVXE MÍRÀN > Lesson 2: Àwvn oríxìí ìkíni fún àwvn ènìyàn




    

Àwvn oríxìí ìkíni fún àwvn ènìyàn (Return)
 B. PERSONAL            Greeting                                 Response

1. Cni tí ó yv nínú ewu       C kú ewu o / C kú àjàb< o        C xé o
2. Cni tí ó nxe nnkan ayz   C kú oríire o (Congrats)         Ire á kárí o/ Adùn náà á kárí o
3. Cni tí ó n xe ìgbéyàwó    Chìn ìyàwó kò ní mcní o         Àxc o
4. Cni tí ó ní oyún                 C kú ìkúnra / Àszkal| ànfàni o  C xé o
5. Cni tí ó bímv                     C kú ewu vmv tuntun o              C xé o /Ire á kárí o
6. Cni tí ó xe vj< ìbí              C kú vdún òní o/Vj< á dal}        C xé o /Àxc o
                                               Àxèyí x|míì
7. Cni tí ó n xì ilé tuntun      C kú ìxílé o / C kú ìnáwó. ilé o     C xe o / Ire á kárí o
8. Cni tí ó x|x| ra vkz         Cmí á lò ó /C kú ìnáwó vkz o       C xe o / Ire á kárí o
9. Cni tí ó gba/jc oyè          Oyè a m<rí o                                    C xe o / Ire á kárí o
10. Cni tí ó x|x| dìde àìsàn C kú ewu o / Àjínde ara ó máa j} o  C xeun o / ooo
11. Cni tí zfz x|                     C kú ìr<jú / C kú àjálù                    C xe o / C kú àdúrò tì
12. Ìkíni fún ikú àgbà            C kú ax|hìndè / C kú àrá f}ra kù o    C xe o / C kú àdúrò tì


© African Studies Institute, University of Georgia.