Home
Overview
Technical Help
Select Unit
>
Unit 8:
>
Lesson 5:
Táyz je Zr} tòótó.
Táyz je Zr} tòótó.
Orúkv zr} mi ni Táyz vmv Adélàjà.
Ó n gbé ní ìlu
Ayétòrò
p|lú mi.
Vmv vdún
márùndínlógbzn
ni
àwa méjéèjì
A jìjv n lv sí ilé ìwé |k< gíga,
A sì
jìjv
n k<
|k< òxèlú
ni.
Mo f}ràn zr} mi
nítorí wí pé
ó j} cni tí a lè
f|hìntì
.
A máa n
ran ara wa l<w<
ní oríxiríxi
znà
.
Àwvn òbi wa
mz
wá ní
zrc kòríkòsùn
.
Gbogbo cbí mi ni w<n mv Táyz àti àwvn
ìdílé
r| dáradára,
G}g} bí
àwvn náà xe mv èmi àti àwvn ìdílé mi dáradára.
Bí ó til| j}
wípé
a kò lè pe ìdílé zr} mi ní
Vl<rz
,
W<n j}
aláàánú
àti
onít|l<rùn
.
Agboóle wvn wà l<nà
Ààfin
Vba Ayétòrò.
Táyz kì í
pur<
, kì í sì
jalè
,
Bó bá xe rí ni yóò wí
.
Mo f}ràn Táyz g}g}bí
ìyekan
.
Kò sí
cnik}ni
tí ò lè
ya
zr} wa,
Táyz je zr}
tòótó
.