|
Xé o
rí Olóyè Vláoyè níb| lánàá?
Akzròhìn:
Nígbàwo ni ìpàdé àwvn òxèlú parí lánàá?
Ayàwòrán:
Ó tó bí aago m<kànlá al}
Akzròhìn:
Àkókò tí w<n parí níjcta náà nì ycn
Ayàwòrán:
Ó ti wá di ìgbà gbogbo kí wvn máa parí ìpàdé wvn
ní aago m<kànlá al}.
Akzròhìn:
B}|ni o. Xé o rí Olóyè Vláoyè níb| lánàá?
Ayàwòrán:
Ó tì o, n kò rí wvn lánàá. Ó tó ìjcrin tí mo ti rí wvn gb|hìn.
Akzròhìn:
Mo máa lv sí <fíìsì wvn
l<la láti lv bère wvn.
Ayàwòrán:
Jzw<, bá mi fún wvn ní àwòrán tí mo
yà w<n
ní ìjcjv.
Akzrzhìn:
Mú u wá, màá fún akzwé wvn
l<la tí mo bá dé b|.
Ayàwòrán:
O xé púpz.
Akzrzhìn:
Kò t<p}. Mo máa rí c ní zs|
tó n bz.
Ayàwòrán:
O digba.
Akzrzhìn:
O digba.
|
|