Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 9: OÚNJC SÍSÈ ÀTI OÚNJC JÍJC > Exercise 1:

EXERCISE 1:                Review Lesson 1 and select the best answer for the following questions:

    1. Irú oúnjc wo ni Vm<wùmí f}ràn jù?

    A. Adalu ni o feran ju
     
    B. Eba ni o feran ju
     
    D. Asaro ni o feran ju
     
    E. Ewa ni o feran ju

    2. Irú ixu wo ní a kò lè fi se |bc?

    A. Ixu gidi
     
    B. Ixu tútù
     
    D. Ixu ewùrà
     
    E. Ixu èsúrú

    3.
    Kíni a máa n xe tí ixu bá ku dí| kí ó jinná?

    A. A lè da ata lílz àti epo pupa dí| si.
     
    B. A lè da omi àti epo pupa dí| si.
     
    D. A lè da ata ati epo dudu dí| si.
     
    E. A lè da ata rodo ati epo ologere dí| si.
     

    4. Bàbá Vmvwùmí kò f}ràn kí ....


    A. Á lo gbogbo ixu nínú àsáró
     
    B. A se gbogbo isu ninu asaro
     
    D. Á tc gbogbo ixu nínú àsáró
     
    E. Á gé gbogbo ixu nínú àsáró
     

    5.
    Kíni yóò j} kí ojú àsáró p<n dáradára

    A. Àlùb<sà tí a fi sí i.
     
    B. Epo pupa tí a fi sí i.
     
    D. Edé pupa tí a fi sí i.
     
    E. Epo gbígbóná tí a fi sí i.
     


© African Studies Institute, University of Georgia.