Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 9: OÚNJC SÍSÈ ÀTI OÚNJC JÍJC > Exercise 3:

EXERCISE 1:                Review Lesson 3 and select the best answer for the following questions:

    1. Irú oúnjc òkèlè wo ni Vmvlvlá f}ràn láti fi vb| |gúsí jc?

    A. Láfún gbígbóná
     
    B. Túwó gbígbóná
     
    D. Àmàlà gbígbóná
     
    E. Iyán gbígbóná

    2. Kíni Ìbídùn f}ràn láti fi vb| |gúsí jc?

    A. Túwó
     
    B. Iyán
     
    D. Àmàlà
     
    E. Cbà

    3.
    Vmvlvlá f} ____ àmàlà

    A. se
     
    B. ro
     
    D. dín
     
    E. yan
     

    4. Kíni Vmvlvlá àti Ìbídùn fi vb| |gúsí jc lónìí?


    A. Túwó             
     
    B. Iyán
     
    D. Àmàlà. 
     
    E. Cbà
     

    5.
    Àkókò wo ni Yorùbá máa sv wípé, “bá mi re!”

    A. Àkókò oúnjc  
     
    B. Àkókò orun
     
    D. Àkókò eré
     
    E. N kò mz
     


© African Studies Institute, University of Georgia.