Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 9:OÚNJC SÍSÈ ÀTI OÚNJC JÍJC > Exercise 5:

Copy/paste the correct answers from the list provided

1. Irú oúnjc wo ni Zgb}ni Afvlábí bèèrè fún?  

Oúnjc òkèlè
Vl<g<rin Náírà
Ob| |gúsí àti ilá dí|
Oríxìí cran m}ta
Wvn lo vw<
Zgb}ni Afvlábí
Vg<rinlénígba Náírà
Omi àti Fántà

 

2.  Iyán eélòó ni Zgb}ni Afvlábí bèèrè fún?  
3. Irú vb| wo ni Zgb}ni Afvlábí bèèrè fún? 
4. Irú cran mélòó ni Zgb}ni Afvlábí bèèrè fún?    
5. Báwo ní Zgb}ni Afvlábí xe jc oúnjc tí w<n rà?
6. Ta ni ó lv sí ilé oúnjc Màma Rísí?         
7. Eélòó ni gbogbo oúnjc Zgb}ni Afvlábí j}?       
8. Irú àwvn ohun mímu wo ni Zgb}ni Afvlábí f}?     


 

© African Studies Institute, University of Georgia.