|
Lesson 1:
Oúnjc tí mo f}ràn jù.
Vm<wùmí: Oúnjc tí mo f}ràn jú ni àsáró.
Awvn elòmíràn ma
n pe ní |bc.
Oríxiríxi ixu ni w<n fi n xe é.
Yàtz
sí ixu gidi, mama mi maá n lo ixu
ewùrà àti ixu pupa.
A lè lo kókò gan
tí a bá f}, xùgb<n a kò lè lo ixu èsuru.
Tí a bá ti bc ixu
yìí tán, a ó ge sí w}w}.
L}yìn èyí, a ó ko sínú ikòkò tí a gbé ka
iná.
A ó sì fi omi ìwznba àti iyz dí|
si.
Tí ó bá ku dí| kí ó jinná,
a ó da ata
lílz àti epo pupa díc
si.
A lè fi àlùb<sà, edé,
cja rírún tàbí ohun èlò vb} míràn tí a bá f} sí i
L}yìn tí gbogbo r| bá ti jinná m< ara wvn tán,
A ó wa fi xíbí tàbí vmvrogùn rò ó pz.
Baba mi kò f}ràn kí a tc gbogbo
ixu inú àsáró
Nítorí náà, a kì í f< gbgogbo ixu tí a bá n xe àsáró ní ilé wa.
Tí ó bá ti jinná dáradárá, a ó bù ú sínú ab< tí ó m<.
Epo pupa tí a fi si yìí yóò j} kí ojú r| p<n dáradára.
|
|