Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 9: Oúnje sísè àti Oúnjc Jíjc. > Lesson 3: Bí A xe n se Vb| |gúsí




    

A xe n se Vb| |gúsí

Ibídùn:         Irú vb| wo ni ò n sè?
Vmvlvlá:    Vb| Cgúsí ni.
Ibídùn:        Báwo ni w<n xe n sè é?
Vmvlvlá:    A ó k<k< lv ata àti |gúsí kúná dáadáa.
                      A ó sì wá wvn pz m< ara wvn
                      L}yìn èyí, a ó dà á sínú epo pupa tí a gbé ka iná.
Ibídùn:        Xe kò ní dín jù?
Vmvlvlá:   Kò gbvdz dín jù
                     L}yìn ìx}jú dí|, a ó bu omi sí i láti j} kí ó jinná.
Ibídùn:       A j} pé vb| dél| nìycn?
Vmvlvlá:   O tì o. A ní láti fi àwvn eròjà bí irú, cja, edé tàbí cran
                      àti àwon ohun èlò míràn tí yóò j} kí vb} dùn si.
Ibídùn:        Xé tí ó bá ti m<ra tán, vb| dél| nìycn?
Vmvlvlá:    B}| ni. Mo f}ràn láti jc vb| |gúsí p|lú àmàlà gbigbona
Ibídùn:      
 Lvlá, Lvlá, O mà ti di vl<w< xíbí o.
                      Cbà ni mo f}ràn láti fi jc c.
Vmvlvlá::   Cbà tàbí iyán náà dára p|lú |gúsí,
                      xùgb<n àmàlà ni mo f} rò lóni i.
                      Xé o ó bá mi re?
Ibídùn:        O dára b}|. N ó wvlé jóko