|
Zgb}ni Afvlábí: C káàsán o, Màma Rísí.
Màmá Rísí: C káàsán, Alàgbà. C wvlé jóko
Zgb}ni Afvlábí: Kí ló wà nílé tí a lè jc?
Màmá Rísí: A ní iyán, cbà, àmàlà, láfún àti fùfú.
Zgb}ni Afvlábí: C fún mi ní iyán vl<g<rin náírà. Irú vb| wo ló wà?
Màmá Rísí: A ní vb| |gúsí, ewédú, ilá, |f<, àti gb|g|rì
Zgb}ni Afvlábí: Irú àwvn cran wo ni c ní?.
Màmá Rísí: A ní cran
màálù, cja, panla, adìyc, ògúfe àti cran ìgb}.
Zgb}ni Afvlábí: Awvn inú cran n k<?
Màmá Rísí: B}|ni, a ní ab<dí, xàkì, |dz, ìfun àti vkàn cran.
Zgb}ni Afvlábí: C fún mi ní vb| }gúsí p|lú ilá dí|.
Mo f} ògúfe oní vg<run náírà p|lú ab<di àti xàkì vl<g<rún náírà.
Màmá Rísí: Xé kí a bu vb| sórí iyán ni tàbí ní ztzztz?
Zgb}ni Afvlábí: Ztzztz ni kí c xe. Kí c sì fún mi ní omi ìxanw<.
Màmá Rísí: Gbogbo | ni a ó dá yín lóhùn nísìsìyí.
Zgb}ni Afvlábí: C ní kí àwvn vmv yín fún mi ní fántà méjì. |
|