Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 10: > Lesson 2: Orúkv mí ni Olúxvlá.




    

Orúkv mí ni Olúxvlá.

Olusola: Orúkv mí ni Olúxvlá vmv Adébáyz.
Táíwò ni àwvn enìyàn n pè mí ní ilé ìwé nítorípé mo j} ìbejì.
Vmv vdún m |d<gbzn ni mí }.
Mo gaìwvn bàtà marun-ún àti àbz.
Mo sanra dí|, mo sì tún pupa.
Iyá mí ni mo fi pupa yì í jv.
Enìyàn dark ni baba mí.
Mo ní ojú búráùn xùgb<n irun orí mí dúdú.
Mo f}ràn láti fi vw< òsì k<w|.
Vw< òsì lílò yìí w<pz nínú ìran baba mí.
Ara mí láti irun orí dé èékánná cs| mi.
Kò sí àbùkù kankan lára mí.
K<ládé ni orúkv àf}s<nà mi.
O j} enìyàn
t}r}, ó ga jù mí lv xùgb<n
kò pupa rárá.
O dúdú bíi kóró isin.
Eyí ni ó j} kí ó wù mí.
Mo nífc r| púpz.