|
Apèjúwe Cbí mi
Abís<lá: Orúkv cbí mi ni Xàngót<lá ní Jobele.
Idílé oníxàngó ni ìdílé bàbá mí.
Xùgb<n nísìsìyi, gbogbo w<n ti di onígbàgb<.
Vmv m}rin ni bàbá baba mí bí xùgb<n baba mi nìkan ni vkùnrin.
Obìnrin ni àwvn ìyókú, baba mí sì ni àk<bí.
Vmv m}rin náà ni baba mí bí, xùgb<n èmi nìkan ni obìnrin.
Vkùnrin ni àwvn ìyókú, èmi sì ni àbígb|yìn.
Mo ní |gb<n vkùnrin m}ta.
Orúkv àwvn |gb<n mi ni Olálékan, Ayzdélé àti Abí<dún.
Aw<n òbí mí ga d<gba xùgb<n bàbá mí tínrín ju mama mí lv.
Awvn |gb<n mí m}t||ta jv bàbá wa púpz xùgb<n ìyá wa ni èmí jv.
Kò yé mi bí vmvkùnrin m}ta xe lè jv bàbá wvn bí i tàwvn |gb<n mi.
Gbogbo wvn ga dí|, w<n tínrín, w<n sì j} onísùúrù.
W<n j} vl<gbvn àti onírèlé enìyàn. Wvn kò ní aápvn rárá.
Mo sanra, mo fi gbogbo nnkan jv mama mi
Mo ní cyinjú títóbi dí|, mo pá èjí iwájú, mo sì tún ní irun gígùn.
Mo j} onínúrere àti onítcríba. Mo sì ní ìt}l<rùn púpz.
Mo mz pé mo ní agídí dí| xùgb<n
Gbogbo enìyàn ni ó mz mí g}g} bí aláàánú.
Iyá mi ni mo fi gbogbo àwvn nnkan wznyí jv, w<n j} arcwà obìnrin. |