Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 11: ÌGBÀ ÀTI ÀKÓKÒ > Exercise 5:

Exercise 5:      Review Lesson 5 and answer the following questions:

 

 

1.Kí ló dé tí Yéwándé f}ràn ìgbà òjò púpz?   
Òjò n rz, xeré nínú ilé
Tí òòrùn bá ràn, a á mú ooru wá
Ó tì, ooru kì í mú ní àkókò òjò
B}| ni, ìgbà ìtura ni ìgbà yí
Nítorípé òòrùn kì í ràn púpz
2.Kí ni òòrùn ní xe p|lú ìgbà òjò?    
3. Orin wo ni àwvn vmvdé máa n kv nígbá òjò?  
4. Xé ìgbà ìtura ni ìgbà òjò?
5. Xé ooru maá n mú púpz ní àkókò òjò?

 

© African Studies Institute, University of Georgia.