Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 11: ÌGBÀ ÀTI ÀKÓKÒ> Exercise 6:

Exercise 6:      Review Lesson 6 and state whether these statements about the various
seasons are TRUE or FALSE (B}| ni tàbí B}| k<).


1. Gbogbo il| máá n tutù nígbà tí òjò bá rz.  B}| ni B}| k<
2. Zpzlvpz àwvn ènìyàn máa wv axv lé axv nítórí òtútù.  B}| ni B}| k<
3. A kì í rí àyípadà nínú ohun gbogbo ní ìwz oòrùn   B}| ni B}| k<
4. Af}f} vy} máa n mú eruku t’ó n fa kùrukùru dání  B}| ni B}| k<
5. Gbogbo koríko, ewéb| àti papa máa n gbc nítorí àìtó omi  B}| ni B}| k<
6. Ètè àti ojú àwvn ènìyàn máa n gbc ní àsìkò Òjò   B}| ni B}| k<
7. Af}f} vy} máa n ti ìwv òrùn wá sí ìwz àríwá ní àsìko zgbcl|  B}| ni B}| k<
8. Àwvn èso àti |f< tútù máa n xzw<n ní àkókò zgbcl| B}| ni B}| k<

 

© African Studies Institute, University of Georgia.