|
Kíni aago wí?
Adéxidà: Káàárz o, B<lánlé.
B<lánlé: Káàárz o, Adésidà.
Nígbàwo lo dìde lórí ìbùsùn?
Adéxidà: Kò tí ì p} púpz.
B<lánlé: Kíni o f} xe lónìí?
Adéxidà: Mo ní láti lv sí ibi ìpàdé kan
láàárz yí.
B<lánlé: Ní aago mélòó?
Adéxidà: Aago m}jv àbz àárz
ni.
B<lánlé: Aago m}jv àbz k|?
Adéxidà: B}| ni o.Kíni aago wí?
B<lánlé: Aago m}jv ku ìx}jú m}|dógún.
Adéxidà: Há! Mo máa p} tí n kò bá xe kíákíá o.
B<lánlé: O ní bí i ìx}jú márùndínláàd<ta.
Adéxidà: Xé o lè bá mi xe cyin méjì?
B<lánlé: Kò burú, j} kí n tètè lv bcrc.
Kò ní gbà ju ìx}jú m}wàá lv.
Adéxidà: O xé púpz o.
B<lánlé: kò t<p}
|
|