Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 11:ÌGBÀ ÀTI ÀKÓKÒ > Lesson 2: Aago mélòó ni o maa n jí láràárz?




    

Aago mélòó ni o maa n jí láràárz?

Oníwadìí:
       Àgò onílé o!
Vláyíwvlá:
   Àgò yà o.
Oníwadìí:
     C kú ojúm< o.
Vláyíwvlá:
   O o. Ta ni c bèèrè o?
Oníwadìí:
     À n xe ìwádìí nípa ìgbé ayé àwvn ak}kz< ni.
Vláyíwvlá:
   C wvlé, c jókòó.
Oníwadìí:
     C xeun.
Vláyíwvlá:
   Irú ìwádìí wo ni | n xe o?
Oníwadìí:
     À n wádìi iye wákàtí tí àwvn ak}kz< fi n sùn lálaal}.
                         A kò ní gbà ju ìx}jú márùn-ún lv.
Vláyíwvlá:
    Ó dára. Mò n gb< o.
Oníwadìí:
     Kí ni orúkv yín?
Vláyíwvlá:
   Orúkv mi ni Vláyíwvlá T}nívlá
Oníwadìí:
     Aago mélòó ni c máa n jí láràárz?
Vláyíwvlá:
   Oríxìí àkókò ni mo máa n jí o.
                         Nígbà míràn, mo lè k<k< ta jí ní aago m}ta àbv òru.
Oníwadìí:
     Xé aago m}ta kò wa yá jù láti jí láàárz?
Vláyíwvlá:
    Rárá o, mo máa n jí kàwé fún wákàtí méjì péré ni.
                          Tí ó bá wá di nnkan bí i aago m}sàn-án aarv ni mo máa n jí.
Oníwadìí:
      Nígbà wo ni c máa n sùn?
Vláyíwvlá:
    Mo maa n sun ní bi i aago mokanla abv alc lojoojumv
Oníwadìí:
      àpàpz, oorun wákàtí mélòó ni c máa n sùn lálaál}?
Vláyíwvlá:
    Mo máa n sùn fún bí i wákàtí méje àbz.
Oníwadìí:
      C xé púpz. Mo tún ní àwvn ìbéèrè méjì miran.
Vláyíwvlá:
    Ó dára. Mò n gb<.

© African Studies Institute, University of Georgia.