Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 11:ÌGBÀ ÀTI ÀKÓKÒ > Lesson 3: Vj< mélòó lówà nínú zx| kan?




    

Vj< mélòó lówà nínú zx| kan?

Zgb}ni Àmzó:      Tinúvlá, vj< mélòó ni ó wà nínú zx| kan?

Tinúvlá:  
               Vj< méje ni ó wà nínú zx| kan.

Zgb}ni Àmzó:
     O kare. Kéhìndé, kini Tinúvlá wi?

Kéhìndé:
               Ó sv wípé vj< méje ló wà nínú zx| kan.

Zgb}ni Àmzó
:      B}| ni. Kéhìndé, zx| mélòó ni ó wà nínú oxù kan?

Kéhìndé:
              Zs| m}rin ni ó wà nínú oxù kan.

Zgb}ni Àmzó
:      O gbà á. Tinúvlá, xé o lè tún ìdáhùn Kéhìndé sv?

Tinúvlá
:                 Ó sv wípé zs| m}rin ni ó wà nínú oxù kan.

Zgb}ni Àmzó
:      Òóótv ni. Ó yá, xé ìwv náà lè sv fún wa iye zs| tó wà nínú vdún kan.

Tinúvlá
:                  Zx| méjìléláàd<ta ni ó wà nínú vdún kan.

Zgb}ni Àmzó:
     Bcc ni, Zx| méjìléláàd<ta ni ó wà nínú vdún kan C káre.

© African Studies Institute, University of Georgia.