|
Ooru
kì í mú púpz ní àkókò òjò.
Tòkunbz: Xé o mv orin tí àwvn vmvdé máa
n kv nígbá òjò?
Yéwándé: Xé orin “òjò n rz, xeré nínú ilé”?
Tòkunbz: B}| ni. Xé ìwv náà f}ràn òjò?
Yéwándé: Mo f}ràn ìgbà òjò púpz
Tòkunbz: Kí ló dé?
Yéwándé: Nítorípé òòrùn kì í ràn púpz.
Tòkunbz: Kí ni òòrùn ní xe p|lú ìgbà òjò?
Yéwándé: O kò mz pé tí òòrùn bá ràn, a á mú ooru wá.
Èmi kò f}ràn ìnilára ooru
rárá.
Tòkunbz: B}| ni, ooru kì í mú púpz ní àkókò òjò.
Yéwándé: Ìgbà ìtura ni ìgbà òjò.
Tòkunbz: J} kí á kvrin “òjò n rz,
xeré nínú ilé”
Yéwándé & Tòkunbz: Òjò n
rz, xeré nínú ilé
Má wvnú òjo,
Kí axv rc, ma bá a utù
Kí òtútù, má ba à mú c z.
|