Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 11: ÌGBÀ ÀTI ÀKÓKÒ > Lesson 6: N kò f}ràn vy} ní àsìkò zgbcl| rárá




    

N kò f}ràn vy} ní àsìkò zgbcl| rárá

Nígbà tí òjò bá rz, gbogbo il| á tutù.
Nígbà míràn, òtútù á mú.
Ní àkókò yìí, zpzlvpz àwvn ènìyàn ni wvn máa wv axv axv,
Kí òtútù má ba à mú wvn.
Xùgb<n ní àsìko zgbcl|, tí af}f} vy} bá ti n ti ìwz àríwá wá sí ìwv òrùn,
A maa n ri àyípadà nínú ohun gbogbo ní ìwz oòrùn.
Fún àpcrc, gbogbo koríko, ewéb| àti pápá ni w<n máa n gbc nítorí àìtó omi.
Af}f} vy} máa n mú eruku t’ó n fa kùrukùru dání.
Ibi gbogbo nínú ilé ni ó máa n tètè dztí nítorí eruku yii.
B}| sì ni ètè àti ojú àwvn ènìyàn máa n gbc.
Irun àwvn elòmíràn á funfun bí i ti àwvn arúgbó.
àkótán, èso àti |f< tútù máa n xzw<n ní àkókò yìí.
Àwvn odò kékèèké tí àwvn vmvdé ti le è xeré, máa n gbc.
N kò f}ràn vy} ní àsìko zgbcl| rárá,
Ìnira tí ó máa n mú wá ti pz jù.

© African Studies Institute, University of Georgia.