Unit 11: ÌGBÀ ÀTI ÀKÓKÒ
-
Unit Dictum
-
Song: Orin Vj< Zs| (Days of
the week song)
-
Song: Òjò má a rz (Rain
keep falling)
-
Song: Orin oxù ní nú vdú n (Song of the
months in the year)
-
Word
Maze: Seasons and Periods Word Search
Unit Dictum: A kò r<j< mú soló kù n, akoko ko
duro denikan.
“We cannot tie down the day, time
waits for nobody.”
Song: Orin
Vj< Zs|
Àì kú , Ajé , Ìxé gun,
Sunday, Monday, Tuesday,
Vj<rú , Vj<bz,
Wednesday, Thursday,
Ctì , Friday,
Àbá m|ta. Saturday.
Song: Òjò
má a rz
Òjò má a
rz (2ce)
Ìtura
lo j}
Òjò má a rz o,
Boba
rz agbado
o yvmv
Bo ba
rz ixu ò lè ta
Bo ba
rz à wa ò lè jc
Bo ba
rz è mi ò lè mu.
Òjò má a rz (2ce)
Ìtura
lo j}
Òjò má a rz o.
Song: Orin
oxù ní nú vdú n
Xé ré ì rè lé eré nà
igbe è bì bí okú dù
agcmo ò gú n vw}w|
ò wà rà tè rè zpc
Seasons and Periods Word Search
1. Print and
see how many of these words you can find in the maze.
2. Use the
opportunity to also mark the right tones and diacritics on the words:
Ogbele
(drought) = Zgbcl| Ojo
(day) = Vj<
3. Remember,
the words can variously be arranged: forward or backward; horizontal or
vertical.
4. Then see how many other Yorù bá words you can find and gloss.
THE WORDS:
Nigbawo? (When?) Akoko (Period/season) Igba (period/season)
Ogbele (drought) Ooru (heat) Ojo (rain)
Idaji (dawn) Aaro (morning) Osan
(afternoon)
Irole (Evening/Dusk) Ale
(Night) Agogo
(clock/time)
Aago (clock/time) Iseju (minute) Wakati
(hour)
Ojo (day) Ose (week) Osu (month)
Odun (year) Ojoojumo
(every day)
THE MAZE:
N J E L O R I L U I D O
U I Y A N A
W S I GB O G
D T GB A G E O GB E W E O
O I A A K O K O K J R G
N D S E W R R J I L U A
B A J E R O P O S E A GB
O J U U J E L I N U R O
R I S O O GB E L E I A O
A W A K A T I R O L GB R
A G A A N I GB A T I R U
W E G U O S A N K O J A
O J O O J U M O B A L E