Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 12: Irìn-àjò, Ibùdó àti Bíbéèrè znà > Exercise 3 (Part 2): Part 1

PART TWO:              Review Lesson 3 and select whether these
                                    statements are TRUE OR FALSE (LÓÒT> NI tabi LÓÒT> K>)


1. Adébísí n lv sí ààfín Vba Lóòt< ni Lóòt< k<
2. Ìyá Àgbà kò lè júwe fún un nítorípé ó xòro púpz Lóòt< ni Lóòt< k<
3. Láti dé ààfin Vba, Adébísí máa wv m<tò, ó máa rin, ó sì máa gun alùpùpù zkadà. Lóòt< ni Lóòt< k<
4. Adébísí máa wv m<tò láti ìta wvn lv sí òpóponá Abí<lá Lóòt< ni Lóòt< k<
5. Adébísí máa gun alúpúpú zkadà láti }gbc àwvn rìwáyà ní òpoponá B<lade lv sí òpóponá Abí<lá Lóòt< ni Lóòt< k<
6. Adébísí lè rìn lv sí ààfín Vba nítorí pé kz jìn rárá Lóòt< ni Lóòt< k<
7. Àafin Vba wà l}gb|} igi zdán nlá kan Lóòt< ni Lóòt< k<
8. Ìyá Àgbà dúp} l<w< Adébísí fún àlàyé znà tí o xe. Lóòt< ni Lóòt< k<
9. Adébísí mà á rìn lv sí ààfín Vba bí Ìyá Àgbà ti júwe Lóòt< ni Lóòt< k<
10. Ìyá Àgbà náà n lv sí ààfín Vba Lóòt< ni Lóòt< k<


© African Studies Institute, University of Georgia.