Home
Overview
Technical Help

Select Unit > Unit 12: Irìn-àjò, Ibùdó àti Bíbéèrè znà > Exercise 4:


Exercise 4:   Select the best answer for each of the following questions: Bí o bá f} lv sí ilé ìwòsàn Olúyoro:

    1. Ìyànà wo ni o máa sv fún oním<tò pé ò n lv?

    A. iyànà ilé ìwòsàn Olúyoro tuntun
     
    B. iyànà ilé ìwòsàn Olúyoro àtij<
     
    D. iyànà ilé alájà m}ta
     
     
    2. Ninu ilé wo ni àwvn àwvn oníxègùn yvyínyvyín wà ni ilé ìwòsàn Olúyoro?

    A. ilé alájà marùn-ún
     
    B. ilé alájà m}rin
     
    D. ilé alájà m}ta
     
     
    3. Eélòó ni owó vkz?

    A. Ogún naira
     
    B. Vgbzn naira
     
    D. Àádvta naira
     
     
    4. Níbo ni àwvn ilé ìtajà tuntun tí ìjvba ìbíl| Ibàdàn x|x| k< wà?

    A. Tààrà lórí òpóponá Olúyoro
     
    B. Lápá ztún òpóponá Tcjúm<lá
     
    D. Lóri i òpóponá Ìjvba ìbíl| Ibàdàn
     
     
    5. Nínu ilé alájà m}ta tí àwvn oníxègùn yvyínyvyín wà, yàrá wo ni oníxègùn yóó ti dá ènìyàn lóhùn?

    A. Yàrá tí ó k}yìn ní apá òsì ni òkè pátápátá
     
    B. Yàrá tí ó k}yìn ní apá ztún ni òkè pátápátá
     
    D. Yàrá tí ó k}yìn ní apá òsì ni ìsal| pátápátá
     
     

 

© African Studies Institute, University of Georgia.