|
Lesson 1: Irìnàjò mi lv sí ìlú Ilé-If|
Adéyínká: Ilú Ekó ni mò n gbé p|lú cbí mi.
Ní òpin zs| tí ó kvjá, mo rin ìrìnàjò lv sí Ilé-If|.
Mo lv bá zr} mi xe ìnáwó òkú bàbá r| àgbà.
Mo wv vkz-èrò láti ibùdóko ní Vj<ta.
Agogo m}fà ààbz àárz ni mo dé ibùdóko yì í,
Xùgb<n ó tó agogo m}jv ààbz kí vkz wa tó kún.
Enìyàn m}san ni vkz yìí lè gbé l|kan.
Zpzlvpz àwvn ontajà ni ó wà ni ibùdóko l<j<ta,
Gbogbo wvn n f} kí a bá àwvn ra vjà oríxiríxi bí i
gúgúrú, búrdì àti àwvn nnkan ìpanu míràn.
Agbèrò ni ó n pe àwa èrò sínú vkz.
L}yìn tí vkz ti kún, agbèrò gba owó vkz l<w< gbogbo wa.
Irínwo naira ni owó vkz cnìkzzkan j}.
L}yìn èyí, agbèrò yv dí| nínu owó yìí, ó sì kó ìyókù fún awakz.
Nígbà tí awakz wá f} má a jade kúrò nínu ibùdóko, àwvn awakz yóókùn juw< sí i,
w<n sì n kí i pé vkz á refó . O tó agogo kan àbz zsán kí a tó dé ìlú Ilé-ìf|.
|
|