|
Mò n lv sí Aàfin Vba
Adébísí: C jzw<, mò n lv sí Aàfín Vba,
Nj} e lè júwe bí mo xe lè dé ib| fún mi.
Ìyá Àgbà: Kò xòro rárá. Wv m<tó láti ìta
wa níbí. Sz kal| ní òpoponá B<lade.
Adébísí: Báwo ni mo xe tún maa rìn?
Ìyá Àgbà: Rìn síwájú dí|, yà sí apá ztún l}gbc àwvn rìwáyà.
Adébísí: L}yìn èyí n kó?
Ìyá Àgbà: Gun alúpúpú zkadà. Yoó sz < ní òpóponá Abí<lá.
Adébísí: Sé n kò lè rìn ni?
Ìyá Àgbà: O tì. O kò lè rìn, nítorí pé ó jìn dí|.
Adébísí: Tí mo bá dé òpóponá Abí<lá n k<?
Ìyá Àgbà: Rìn síwájú dí|, kí o yà sí apá òsì, l}yìn èyí wà á rí igi zdán
nlá kan, |gb} igi yìí ni ààfin vba wà.
Adébísí: C xeun, mà á rìn bí c ti júwe.
Ìyá Àgbà: O dàbz, má p|}.
Adébísí: O dábz o.
|
|